Vairagi

Ancient Order of Vairagi, tí a tún ń pè ní Vairagi Order àti Vairagi Adepts, jẹ arákẹgbẹ àwọn ECK Masters.

Vairag túmọ̀ sí Ìyapa (Detachment). Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwà ìní pàtàkì márùn-ún ìwà nínú Eckankar.

Mahanta, ẹni tí a ń pè ní Living ECK Master, ni olórí ẹgbẹ́ náà, àti gbogbo àwọn iṣẹ́-ṣiṣe àwọn ECK Masters ni a ṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀.

Kò sí ohun mìíràn bí kò ṣe fígbé ayé ènìyàn ga nípa ti ẹ̀mí ni ète ti àwọn ECK Masters wọ̀nyí.